Yoruba

Ẹ k'áàbọ̀ sí CE Swídìn

A nran awọn oníbàárà lọwọ káàkiri àgbáyé lati sàyípo ilẹ̀ ìsòwò Swídìsh. Àwọn alájùmọ̀sọ̀rọ̀ wa fi asikò silẹ̀ lati ni ìmọ̀ dáradára nipa ilé-isẹ́ rẹ, àwọn ẹ̀rọ ati àwọn àfojúsùn ilé-isẹ́. Àwọn itánsòro ti a fifún yin yóò bá awọn ohun tí ẹ nílò aláìlẹ́gbẹ́ mu.
Swídìn jẹ́ orilẹ̀-èdè tó dàgbà gidigidi tó sì lérè pẹ̀lú ànfààní àilópin – ibi tó pé fún ọ láti wà lágbàáyé ki o si se àwári àwọn ọjà tuntun.
Jẹ́ alábàásisẹpọ̀ pẹ̀lú wa. A dúró sinsin láti tọ yin sọna ni ọ̀nà gbogbo.

1 Forbes láìpẹ́ yìí dárúkọ Swídìn gẹ́gẹ́bí orílẹ̀-èdè tó dára jùlọ láyé lati s’òwò – ilẹ̀ ọlọ́ràá fún àwọn olùfowopamọ́

2 Swídìn ni pà kápítà GDP Dọ́là Ẹgbẹ̀rún Mẹ́tàdinlọ́gọ́ta, Ó dín Mẹ́rinlélógójì ($56,956) tó sì ni idiwọ̀n igbé ayé tó ga jùlọ nibiki láyé

3 Isúná owó díjítà tó ga jùlọ ni Yúrópù ati ilú tó tayọ láàárín agbègbè náà ní ti àìmálo owó

4 Ìfihan Ìdije Kárí-ayé ti to Swídìn gẹ́gẹ́bi orilẹ̀-èdè tí ètò ìsúná rẹ̀ ni ìdíje jùlọ láyé

5 Swídìn ni a mọ̀ sí orilẹ̀-èdè EU tí ó ndá nǹkan silẹ̀ jùlọ, pẹ̀lú nọ́mbà pétẹ́ntì pà kápítà tó ga jùlọ

6 Swídìn wà ní ipò tó dára ju orílẹ̀-èdè míràn lọ láti músẹ àwọn Ìlepa Ìdàgbàsókè Ọlọ́jọ́pípẹ ti UN

ŃJÙMỌ̀SỌ̀RỌ̀

ÌTÚPALẸ ỌJÀ

ÌWÁDÌÍ

ỌFÍSÌ AFOJÚUNÚSE

ÌTUMỌ̀

0
AWỌN ỌDÚN NINÚ ÌSÒWÒ NÁÀ
0
ÀWỌN ẸNIKEJI Ọ̀JỌ̀GBỌ́N
0
ÀWỌN ONIBÀÁRÀ TÓ PEGEDÉ
0 %
Ẹ̀RÍ ÌTẸNILỌ́RÙN
Àsà Àwọn Ìtánsòro
Oníbàárà kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ - Isẹ́ àkànse kọ̀ọ̀kan ló yàtọ̀ - Ìdí nìyẹn ti a fi ngbìyànjú lati fún yín ni àsà àwọn ìtànsòro, lati bá àìní ati ifójúsùn rẹ tí kò lẹ́gbẹ́ pàdé
Ìmọ̀ abẹ́lé
Àsopọ̀ tímọ́tímọ́ wa pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka ilé-isẹ́ ìjọba Swedish, àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ati àwọn ilé-isẹ́ nràn wa lọ́wọ́ láti tánsòro rẹ kíákíá ati pẹ̀lú ìrọ̀rùn
Lo Ànfààni Kíkọ́sẹ́mọsẹ́ Wa
Jẹ́ká fún ọ ni àtilẹhìn láti s'àseyọri - Àwọn àwòsínú ti a ti kójọ lọ́pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́hin jẹ́ kọ́kọ́rọ́ sí àseyọri wa ni Sweden
Àwọn ìdiwọn ati àwòsínú
Àwọn ìlànà ati ìse tí a dá-lábàá ló ní àwọn ọnà lati diwọ̀n ìyọrísí tí wọn ni lórí àwọn àfojúsùn isòwò ati itajà rẹ
Isẹ́ Ìtayọ
Àwọn èsì wa ní àsopọ̀ tààrà sí dídára sí àwọn isẹ́ wa, ati paríparí sí àseyọrí rẹ - A wà níbí láti ràn ọ́ lọ́wọ́ ni gbogbo ọ̀nà

Ìròhìn tuntun

Loading RSS Feed
Jẹ́k'á s'àwárí gbogbo ohun tó seése!

Kàn sí wa láti sàwári díẹ̀ sii

error: Innehållet är skyddat!